Stats: 41964 members, 38256 topics. Cached on: Monday, 25th September 2023 HOMEGENERALEDUCATIONNEWSMusicTECHNOLOGY |
2019 WAEC GCE Igbo, Yoruba and Hausa Answers |
---|
(0) (Reply) (Create New Topic) (Go Down)
2019 WAEC GCE Igbo, Yoruba and Hausa Answers by Flex: 1:00 pm On September 5, 2019 |
2019 WAEC GCE Igbo, Yoruba and Hausa Answers are now available. N400 only will grant you access to the answers. Buy MTN recharge card of N400 and send the pin together with the subject paid for to 09067385575. If you have already paid, click on the button below to view the answers. Don’t have money to pay? Share this post with all your friends writing WAEC and you might get it for free. ![]() You Might Also Like These:
FREE WAEC GCE Igbo, Yoruba and Hausa AnswersYoruba Answers ![]() ![]() ![]() ![]() ![]() ![]() FIFI OBA JE: Leyin osun meta tabi mefa ti oba kan ti waja ni awon afobaje yoo bere sii fi ikunlukun nipa pe to akoko ki won ni oba miiran. Awon afobaje yii tun ni oruko orisirisi ti a n pe won ni ilu miiran an pe won ni “IWARAFA” “IKORI MESAN” “ABOBAPE” ati bee be lo. Awon afobaje ni yoo pe idile oba ni ilu naa pe ki won fun won ni eniyan won eyi eni ti oba to si lati je, sugbon ife lati gun ori ite oba yoo mu ki opo eniyan naga si jije oba. Bi opolopo eniyan owo ni idile oba pe won fee je oba, awon afobaje yoo se iwadi si oro naa won yoo losi odo onifa tabi odede omoran lati le yan okan ti o maa tu ilu lara ninu awon ti n dun oye oba. Ni opolopo ilu akogbodo fi aafin sile lasan idi ni ti a fi n yan iya arugbo kan lati maa iba eto ti o ba le se ni aafin. Sugbon ni aye ode oni, olaju to de ode oni nipe ti oba ilu kan ba waja se ni awon afobaje ilu yoo ranse si awon idile ti o kan lati maa mura sile wipe idile ti o kan lati maa mura sile wipe idile won ni oba kan, won yoo si ko oruko okunrin ti o ba wa ni ile naa, won yo si mu lo si odo awon afobaje, ni aye atijo eni ti ifa ba ti mu ni yoo je oba ni ilu naa. Sugbon ni aye ode oni nigba ti won ba ti ko oruko lo si odo awon afobaje. Awon ti o ba lowo ju ni aarin awon ti won ko oruko won yii ni won maa mu, nitoripe olaju ti de eyi lo mu ki won si gba oye ninu iwe je oba laye ode oni. Ni aye ode oni won si tun maa n mu awon ti o ba lowo ninu idile ti oba ba to si nitori won ko fe maa fi otosi je oba laye o de oni mo. A si tun gbo wipe ni aye atijo a ko gbodo fi aafin sile lasan, eyi si n sele ni aye ode oni, ni aye atijo iya arugbo kan ni won ma fi n se adele, sugbon olaju ti de, ni aye ode oni eto isejoba aye ode oni ni wipe ki won maa yan odomobirin ni opolopo ilu ni ile Yoruba. More Loading……………..
(3bi) (3bii) (4) (4a) (4b) |
(0) (Reply)
Federal University of Agriculture, Zuru, Kebbi State 2022/2023 Post / Federal University of Health Technology, Otukpo Benue State 2022/2023 Post / Usumanu Danfodiyo University Sokoto UDUSOK 2022/2023 Post Utme Screening form is out /
(Go Up)
Sections: News (1) Technology Education (2) Earboard - Copyright @ 2016 - 2023 Forumer. All rights reserved. See How To Advertise. DMCA Content Removal. Disclaimer: Every member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Earbaord. |